•_____Òwe Yorùbá______
Kò sí bí ilẹ̀ ṣe lè mọ́ tó, kó máà ṣú, kò dẹ̀ sí bí ilẹ̀ ṣe lè ṣú tó, kó máà mọ́.
______Translation________
No matter how bright the day, night will fall, and no matter how dark the night, it will yet become dawn.
_____Moral_____
No condition or situation is permanent; keep hope alive.
•___Òwe Yorùbá_____
Ẹni bá pẹ́ nígbó á rí ìríkúùrí.
______Translation____
Whoever tarries long in the forest, will have strange experiences.
______Moral______
Delays may lead to unusual results; make hay while the sun shines.
•____Owe____
Ojú tí kò rí yànná yànná iná, yẹ̀rẹ̀ yẹ̀rẹ̀ oòrùn, kì í rí yìndìn yindin idẹ.
______Translation____
A pair of eyes that won't endure the fiery flames of fire and the searing glare of the sun, can't enjoy the glittering (beauty) of brass.
____Moral____
No pain, no gain;
No guts, no glory.
•____Òwe___
Àṣegbé kànkan ò sí, àṣepamọ́ ló wà.
___Translation_____
Actions may be covered up but cannot be carried out with impunity.
____Moral____
Nothing can be permanently covered up.
•_____Àkànlò Èdè_____
Òkú tí ẹ sin, ẹsẹ̀ rẹ̀ ti yọ síta.
_____Idioms____
The feet of the corpse you buried is sticking out.
_____Translation_____
"Àṣírí yín ti tú."
"Your secret is out in the open."
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
No comments:
Post a Comment
WHAT IS YOUR OPINION